1 Kronika 6:74
1 Chronicles 6:74 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Láti ẹ̀yà Aṣeri wọ́n gba Maṣali, Abdoni,
1 Chronicles 6:74 in English
1 Chronicles 6:74 · Berean Standard Bible
From the tribe of Asher they were given Mashal, Abdon,
Context
72Láti ẹ̀yà Isakari wọ́n gba Kedeṣi, Daberati 73Ramoti àti Anenu, lápapọ̀ pẹ̀lú pápá oko tútù ilẹ̀ wọn. 74Láti ẹ̀yà Aṣeri wọ́n gba Maṣali, Abdoni, 75Hukoki àti Rehobu lápapọ̀ pẹ̀lú pápá oko tútù ilẹ̀ wọn. 76Pẹ̀lú láti ẹ̀yà Naftali wọ́n gba Kedeṣi ní Galili, Hammoni àti Kiriataimu, lápapọ̀ pẹ̀lú pápá oko tútù ilẹ̀ wọn.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.