1 Kronika 6:73
1 Chronicles 6:73 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Ramoti àti Anenu, lápapọ̀ pẹ̀lú pápá oko tútù ilẹ̀ wọn.
1 Chronicles 6:73 in English
1 Chronicles 6:73 · Berean Standard Bible
Ramoth, and Anem, together with their pasturelands.
Context
71Àwọn ará Gerṣoni gbà nǹkan wọ̀nyí.
Láti ààbọ̀ ẹ̀yà ti Manase wọ́n gba Golani ní Baṣani àti pẹ̀lú Aṣtarotu, lápapọ̀ pẹ̀lú pápá oko tútù wọn. 72Láti ẹ̀yà Isakari wọ́n gba Kedeṣi, Daberati 73Ramoti àti Anenu, lápapọ̀ pẹ̀lú pápá oko tútù ilẹ̀ wọn. 74Láti ẹ̀yà Aṣeri wọ́n gba Maṣali, Abdoni, 75Hukoki àti Rehobu lápapọ̀ pẹ̀lú pápá oko tútù ilẹ̀ wọn.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.