1 Kronika 6:67
1 Chronicles 6:67 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Ní òkè orílẹ̀-èdè Efraimu, a fún wọn ní Ṣekemu (ìlú ńlá ti ààbò), àti Geseri
1 Chronicles 6:67 in English
1 Chronicles 6:67 · Berean Standard Bible
They were given Shechem (a city of refuge)* with its pasturelands in the hill country of Ephraim, and Gezer,
Context
65Láti ẹ̀yà Juda, Simeoni àti Benjamini ni a pín ìlú tí a ti dárúkọ wọn sẹ́yìn fún. 66Lára àwọn ìdílé Kohati ni a fún ní ìlú láti ẹ̀yà Efraimu gẹ́gẹ́ bí ìlú agbègbè wọn. 67Ní òkè orílẹ̀-èdè Efraimu, a fún wọn ní Ṣekemu (ìlú ńlá ti ààbò), àti Geseri 68Jokimeamu, Beti-Horoni. 69Aijaloni àti Gati-Rimoni lápapọ̀ pẹ̀lú pápá oko tútù ilẹ̀ wọn.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.