1 Kronika 6:53
1 Chronicles 6:53 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Sadoku ọmọ rẹ̀ àti Ahimasi ọmọ rẹ̀.
1 Chronicles 6:53 in English
1 Chronicles 6:53 · Berean Standard Bible
Zadok his son, and Ahimaaz his son.
Context
51Bukki ọmọ rẹ̀,
Ussi ọmọ rẹ̀, Serahiah ọmọ rẹ̀, 52Meraioti ọmọ rẹ̀, Amariah ọmọ rẹ̀,
Ahitubu ọmọ rẹ̀, 53Sadoku ọmọ rẹ̀
àti Ahimasi ọmọ rẹ̀. 54Wọ̀nyí ni ibùgbé wọn tí a pín fún wọn gẹ́gẹ́ bí agbègbè wọn (tí a fi lé àwọn ìran ọmọ Aaroni lọ́wọ́ tí ó wá láti ẹ̀yà Kohati, nítorí kèké alákọ́kọ́ jẹ́ tiwọn). 55A fún wọn ní Hebroni ní Juda pẹ̀lú àyíká pápá oko tútù ilẹ̀ rẹ̀.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.