1 Kronika 6:31
1 Chronicles 6:31 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Èyí ní àwọn ọkùnrin Dafidi tí a fi sí ìdí orin nínú ilé Olúwa lẹ́yìn tí àpótí ẹ̀rí ti wá láti sinmi níbẹ̀.
1 Chronicles 6:31 in English
1 Chronicles 6:31 · Berean Standard Bible
These are the men David put in charge of the music in the house of the LORD after the ark rested there.
Context
29Àwọn ìran ọmọ Merari:
Mahili, Libni ọmọ rẹ̀.
Ṣimei ọmọ rẹ̀, Ussa ọmọ rẹ̀. 30Ṣimea ọmọ rẹ̀, Haggiah ọmọ rẹ̀
àti Asaiah ọmọ rẹ̀. 31Èyí ní àwọn ọkùnrin Dafidi tí a fi sí ìdí orin nínú ilé Olúwa lẹ́yìn tí àpótí ẹ̀rí ti wá láti sinmi níbẹ̀. 32Wọ́n jíṣẹ́ pẹ̀lú orin níwájú àgọ́ ìpàdé títí tí Solomoni fi kọ́ ilé Olúwa ní Jerusalẹmu. Wọ́n ṣe iṣẹ́ ìsìn wọn ní ìbámu pẹ̀lú ìlànà tí a fi lélẹ̀ fún wọn. 33Wọ̀nyí ni àwọn ọkùnrin tí ó sìn pẹ̀lú ọmọ wọn.
Láti ọ̀dọ̀ àwọn ará Kohati:
Hemani olùkọrin,
ọmọ Joẹli, ọmọ Samuẹli,
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.