1 Kronika 26:3
1 Chronicles 26:3 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Elamu ẹlẹ́ẹ̀karùnún, Jehohanani ẹlẹ́ẹ̀kẹfà àti Elihoenai ẹlẹ́ẹ̀keje.
1 Chronicles 26:3 in English
1 Chronicles 26:3 · Berean Standard Bible
Elam the fifth, Jehohanan the sixth, and Eliehoenai the seventh.
Context
1Àwọn ìpín tí àwọn olùtọ́jú ẹnu-ọ̀nà.
Láti ìran Kora:
Meṣelemiah ọmọ Kore, ọ̀kan lára àwọn ọmọ Asafu. 2Meṣelemiah ní àwọn ọmọkùnrin:
Sekariah àkọ́bí, Jediaeli ẹlẹ́ẹ̀kejì,
Sebadiah ẹlẹ́ẹ̀kẹta, Jatnieli ẹlẹ́ẹ̀kẹrin, 3Elamu ẹlẹ́ẹ̀karùnún, Jehohanani ẹlẹ́ẹ̀kẹfà
àti Elihoenai ẹlẹ́ẹ̀keje. 4Obedi-Edomu ni àwọn ọmọkùnrin pẹ̀lú:
Ṣemaiah àkọ́bí, Jehosabadi ẹlẹ́ẹ̀kejì,
Joah ẹlẹ́ẹ̀kẹta, Sakari ẹlẹ́ẹ̀kẹrin,
Netaneli ẹlẹ́ẹ̀karùnún, 5Ammieli ẹ̀kẹfà,
Isakari èkeje àti Peulltai ẹ̀kẹjọ.
(Nítorí tí Ọlọ́run ti bùkún Obedi-Edomu).
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.