1 Kronika 24:18
1 Chronicles 24:18 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
ẹ̀kẹtàlélógún sì ni Delaiah, ẹ̀kẹrìnlélógún sì ni Maasiah.
1 Chronicles 24:18 in English
1 Chronicles 24:18 · Berean Standard Bible
the twenty-third to Delaiah, and the twenty-fourth to Maaziah.
Context
16ẹ̀kọkàndínlógún sì ni Petahiah,
ogún sì ni Jeheskeli, 17ẹ̀kọkànlélógún sì ni Jakini,
ẹ̀kẹrìnlélógún sì ni Gamuli, 18ẹ̀kẹtàlélógún sì ni Delaiah,
ẹ̀kẹrìnlélógún sì ni Maasiah. 19Àwọn wọ̀nyí ni a yàn fún iṣẹ́ ìsìn nígbà tí wọ́n wọ ilé Olúwa, gẹ́gẹ́ bí ìlànà àti àṣẹ tí a ti fi fún wọn láti ọwọ́ baba ńlá wọn Aaroni gẹ́gẹ́ bí Olúwa, Ọlọ́run Israẹli, tí pàṣẹ fun un. 20Ìyókù àwọn ọmọ Lefi.
Láti ọ̀dọ̀ àwọn ọmọ Amramu: Ṣubaeli
láti ọ̀dọ̀ àwọn ọmọ Ṣubaeli; Jehdeiah.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.