1 Kronika 2:7
1 Chronicles 2:7 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Àwọn ọmọ Karmi: Akani, ẹni tí ó mú ìyọnu wá sórí Israẹli nípa ẹ̀ṣẹ̀ ìfibú lórí mímú ohun ìyàsọ́tọ̀.
1 Chronicles 2:7 in English
1 Chronicles 2:7 · Berean Standard Bible
The son * of Carmi: Achar,* who brought trouble upon Israel by violating the ban on devoted things.
Context
5Àwọn ọmọ Peresi:
Hesroni àti Hamulu. 6Àwọn ọmọ Sera:
Simri, Etani, Hemani, Kalkoli àti Dara, gbogbo wọn jẹ́ márùn-ún. 7Àwọn ọmọ Karmi:
Akani, ẹni tí ó mú ìyọnu wá sórí Israẹli nípa ẹ̀ṣẹ̀ ìfibú lórí mímú ohun ìyàsọ́tọ̀. 8Àwọn ọmọ Etani:
Asariah. 9Àwọn ọmọ tí a bí fún Hesroni ni:
Jerahmeeli, Ramu àti Kalebu.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.