Native Bible

1 Chronicles 2:6 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Àwọn ọmọ Sera: Simri, Etani, Hemani, Kalkoli àti Dara, gbogbo wọn jẹ́ márùn-ún.

1 Chronicles 2:6 in English

1 Chronicles 2:6 · Berean Standard Bible

The sons of Zerah: Zimri,* Ethan, Heman, Calcol, and Dara *—five in all.

Context

4Tamari, aya ọmọbìnrin Juda, ó sì bí Peresi àti Sera sì ní ọmọ márùn-ún ní àpapọ̀. 5Àwọn ọmọ Peresi: Hesroni àti Hamulu. 6Àwọn ọmọ Sera: Simri, Etani, Hemani, Kalkoli àti Dara, gbogbo wọn jẹ́ márùn-ún. 7Àwọn ọmọ Karmi: Akani, ẹni tí ó mú ìyọnu wá sórí Israẹli nípa ẹ̀ṣẹ̀ ìfibú lórí mímú ohun ìyàsọ́tọ̀. 8Àwọn ọmọ Etani: Asariah.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.