1 Kronika 15:9
1 Chronicles 15:9 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Ọgọ́rin nínú àwọn ọmọ Hebroni; Elieli olórí àti àwọn ẹbí rẹ̀.
1 Chronicles 15:9 in English
1 Chronicles 15:9 · Berean Standard Bible
from the Hebronites, Eliel the chief and 80 of his relatives;
Context
7Àádóje nínú àwọn ọmọ Gerṣoni;
Joẹli olórí àti àwọn ẹbí rẹ̀. 8Igba nínú àwọn ọmọ Elisafani;
Ṣemaiah olórí àti àwọn ẹbí rẹ̀. 9Ọgọ́rin nínú àwọn ọmọ Hebroni;
Elieli olórí àti àwọn ẹbí rẹ̀. 10Méjìléláàádọ́fà nínú àwọn ọmọ Usieli;
Amminadabu olórí àti àwọn ẹbí rẹ̀. 11Dafidi sì ránṣẹ́ pe Sadoku, Abiatari tí wọ́n jẹ́ àlùfáà, àti Urieli, Asaiah. Joẹli, Ṣemaiah, Elieli àti Amminadabu tí wọ́n jẹ́ Lefi.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.