1 Kronika 15:6
1 Chronicles 15:6 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Igba ó lé ogún nínú àwọn ọmọ Merari; Asaiah olórí àti àwọn ẹbí rẹ̀.
1 Chronicles 15:6 in English
1 Chronicles 15:6 · Berean Standard Bible
from the Merarites, Asaiah the chief and 220 of his relatives;
Context
4Wọ̀nyí ni àwọn ọmọ Aaroni àti àwọn ọmọ Lefi tí Dafidi péjọ papọ̀. 5Ọgọ́fà nínú àwọn ọmọ Kohati;
Urieli olórí àti àwọn ẹbí rẹ̀. 6Igba ó lé ogún nínú àwọn ọmọ Merari;
Asaiah olórí àti àwọn ẹbí rẹ̀. 7Àádóje nínú àwọn ọmọ Gerṣoni;
Joẹli olórí àti àwọn ẹbí rẹ̀. 8Igba nínú àwọn ọmọ Elisafani;
Ṣemaiah olórí àti àwọn ẹbí rẹ̀.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.