Native Bible

1 Chronicles 1:50 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Nígbà tí Baali-Hanani kú, Hadadi ni ó jẹ ọba ní ipò rẹ̀. Orúkọ ìlú rẹ̀ ni Pau; orúkọ ìyàwó sì ni Mehetabeeli ọmọbìnrin Matiredi, ọmọbìnrin Mesahabu.

1 Chronicles 1:50 in English

1 Chronicles 1:50 · Berean Standard Bible

When Baal-hanan died, Hadad reigned in his place. His city was named Pau,* and his wife’s name was Mehetabel daughter of Matred, the daughter of Me-zahab.

Context

48Samla sì kú, Saulu ti Rehoboti létí odò sì jẹ ọba ní ipò rẹ̀. 49Nígbà tí Saulu kú, Baali-Hanani, ọmọ Akbori jẹ ọba ní ipò rẹ̀. 50Nígbà tí Baali-Hanani kú, Hadadi ni ó jẹ ọba ní ipò rẹ̀. Orúkọ ìlú rẹ̀ ni Pau; orúkọ ìyàwó sì ni Mehetabeeli ọmọbìnrin Matiredi, ọmọbìnrin Mesahabu. 51Hadadi sì kú pẹ̀lú. Àwọn baálẹ̀ Edomu ni: baálẹ̀ Timna, baálẹ̀ Alfa, baálẹ̀ Jeteti 52baálẹ̀ Oholibama, baálẹ̀ Ela, baálẹ̀ Pinoni.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.