1 Kronika 1:51
1 Chronicles 1:51 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Hadadi sì kú pẹ̀lú. Àwọn baálẹ̀ Edomu ni: baálẹ̀ Timna, baálẹ̀ Alfa, baálẹ̀ Jeteti
1 Chronicles 1:51 in English
1 Chronicles 1:51 · Berean Standard Bible
Then Hadad died. Now the chiefs of Edom were Timna, Alvah, Jetheth,
Context
49Nígbà tí Saulu kú, Baali-Hanani, ọmọ Akbori jẹ ọba ní ipò rẹ̀. 50Nígbà tí Baali-Hanani kú, Hadadi ni ó jẹ ọba ní ipò rẹ̀. Orúkọ ìlú rẹ̀ ni Pau; orúkọ ìyàwó sì ni Mehetabeeli ọmọbìnrin Matiredi, ọmọbìnrin Mesahabu. 51Hadadi sì kú pẹ̀lú.
Àwọn baálẹ̀ Edomu ni:
baálẹ̀ Timna, baálẹ̀ Alfa, baálẹ̀ Jeteti 52baálẹ̀ Oholibama, baálẹ̀ Ela, baálẹ̀ Pinoni. 53Baálẹ̀ Kenasi, baálẹ̀ Temani, baálẹ̀ Mibsari,
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.