Rutu 4:18
Ruth 4:18 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Èyí ni ìran Peresi: Peresi ni baba Hesroni,
Ruth 4:18 in English
Ruth 4:18 · Berean Standard Bible
Now these are the generations of Perez: Perez was the father of Hezron,
Context
16Naomi sì gbé ọmọ náà lé orí ẹsẹ̀ rẹ̀, ó sì ń tọ́jú rẹ̀. 17Àwọn obìnrin àdúgbò sì wí pé, “A bí ọmọkùnrin kan fún Naomi.” Wọ́n sì pe orúkọ rẹ̀ ní Obedi. Òun sì ni baba Jese tí í ṣe baba Dafidi. 18Èyí ni ìran Peresi:
Peresi ni baba Hesroni, 19Hesroni ni baba Ramu,
Ramu ni baba Amminadabu 20Amminadabu ni baba Nahiṣoni,
Nahiṣoni ni baba Salmoni,
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.