Saamu 97:9
Psalms 97:9 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Nítorí pé ìwọ, Olúwa, ni ó ga ju gbogbo ayé lọ ìwọ ni ó ga ju gbogbo òrìṣà lọ.
Psalms 97:9 in English
Psalms 97:9 · Berean Standard Bible
For You, O LORD, are Most High over all the earth; You are exalted far above all gods.
Context
7Gbogbo àwọn tí ń sin ère fínfín ni ojú yóò tì,
àwọn tí ń fi ère gbéraga,
ẹ máa sìn ín, gbogbo ẹ̀yin ọlọ́run! 8Sioni gbọ́, inú rẹ̀ sì dùn
inú àwọn ilé Juda sì dùn,
nítorí ìdájọ́ rẹ, Olúwa. 9Nítorí pé ìwọ, Olúwa, ni ó ga ju gbogbo ayé lọ
ìwọ ni ó ga ju gbogbo òrìṣà lọ. 10Jẹ kí gbogbo àwọn tí ó fẹ́
Olúwa, kórìíra ibi, ó pa ọkàn àwọn ènìyàn mímọ́ rẹ̀ mọ́
ó gbà wọ́n ní ọwọ́ àwọn ènìyàn búburú. 11Ìmọ́lẹ̀ tàn sórí àwọn olódodo
àti ayọ̀ nínú àlàyé ọkàn.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.