Saamu 88:10
Psalms 88:10 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Ìwọ ó fi iṣẹ́ ìyanu rẹ hàn fún òkú bi? Àwọn òkú yóò ha dìde láti yìn ọ́ bí?
Psalms 88:10 in English
Psalms 88:10 · Berean Standard Bible
Do You work wonders for the dead? Do departed spirits rise up to praise You? Selah
Context
8Ìwọ tí gba ọ̀rẹ́ mi tí ó súnmọ́ mi kúrò lọ́wọ́ mi
ìwọ sì sọ mi di ìríra sí wọn.
A há mi mọ́, èmi kò sì le è jáde; 9ojú mi káàánú nítorí ìpọ́njú.
Mo kígbe pè ọ́, Olúwa, ní gbogbo ọjọ́;
mo na ọwọ́ mi jáde sí ọ. 10Ìwọ ó fi iṣẹ́ ìyanu rẹ hàn fún òkú bi?
Àwọn òkú yóò ha dìde láti yìn ọ́ bí? 11A ó ha fi ìṣeun ìfẹ́ rẹ hàn ní ibojì bí,
tàbí òtítọ́ rẹ ní ipò ìparun? 12A ha lè mọ iṣẹ́ ìyanu rẹ ní òkùnkùn bí
àti òdodo rẹ ní ilẹ̀ ìgbàgbé?
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.