Saamu 86:6
Psalms 86:6 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Gbọ́ àdúrà mi, Olúwa; tẹ́tí sí ẹkún mi fún àánú.
Psalms 86:6 in English
Psalms 86:6 · Berean Standard Bible
Hear my prayer, O LORD, and attend to my plea for mercy.
Context
4Mú ayọ̀ wà fún ìránṣẹ́ rẹ,
nítorí ìwọ, Olúwa,
ni mo gbé ọkàn mí sókè sí. 5Ìwọ ń dáríjì, ìwọ sì dára, Olúwa,
ìwọ sì ṣàánú fún gbogbo àwọn tí ń ké pè ọ́. 6Gbọ́ àdúrà mi, Olúwa;
tẹ́tí sí ẹkún mi fún àánú. 7Ní ọjọ́ ìpọ́njú mi èmi yóò pè ọ́,
nítorí ìwọ yóò dá mi lóhùn. 8Nínú àwọn òrìṣà kò sí ẹni tí ó dàbí i rẹ, Olúwa:
kò sí àwọn iṣẹ́ tí a lè fiwé tìrẹ.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.