Native Bible

Psalms 83:9 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Ṣe sí wọn bí ìwọ ti ṣe sí Midiani bí o ti ṣe sí Sisera àti Jabini ní odò Kiṣoni,

Psalms 83:9 in English

Psalms 83:9 · Berean Standard Bible

Do to them as You did to Midian, as to Sisera and Jabin at the River Kishon,

Context

7Gebali, Ammoni àti Amaleki, Filistia, pẹ̀lú àwọn ènìyàn Tire. 8Asiria pẹ̀lú ti darapọ̀ mọ́ wọn láti ran àwọn ọmọ Lọti lọ́wọ́. Sela. 9Ṣe sí wọn bí ìwọ ti ṣe sí Midiani bí o ti ṣe sí Sisera àti Jabini ní odò Kiṣoni, 10ẹni tí ó ṣègbé ní Endori tí wọn sì dàbí ààtàn ní orí ilẹ̀. 11Ṣe àwọn ọlọ́lá wọn bí Orebu àti Seebu, àwọn ọmọ-aládé wọn bí Seba àti Salmunna,

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.