Native Bible

Psalms 81:4 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Èyí ni àṣẹ fún Israẹli, àti òfin Ọlọ́run Jakọbu.

Psalms 81:4 in English

Psalms 81:4 · Berean Standard Bible

For this is a statute for Israel, an ordinance of the God of Jacob.

Context

2Ẹ mú orin mímọ́, kí ẹ sì mú ìlù wá, tẹ dùùrù dídùn pẹ̀lú ohun èlò orin mímọ́. 3Ẹ fún ìpè ní oṣù tuntun àní nígbà tí a yàn; ní ọjọ́ àjọ wa tí ó ní ìrònú. 4Èyí ni àṣẹ fún Israẹli, àti òfin Ọlọ́run Jakọbu. 5Ó fi múlẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ìlànà fún Josẹfu nígbà tí ó la ilẹ̀ Ejibiti já. Níbi tí a ti gbọ́ èdè tí kò yé wa. 6Ó wí pé, “Mo gbé àjàgà kúrò ní èjìká yín, a tú ọwọ́ wọn sílẹ̀ kúrò nínú apẹ̀rẹ̀.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.