Native Bible

Psalms 79:7 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

nítorí wọ́n ti run Jakọbu wọ́n sì sọ ibùgbé rẹ di ahoro.

Psalms 79:7 in English

Psalms 79:7 · Berean Standard Bible

for they have devoured Jacob and devastated his homeland.

Context

5Nígbà wo, Olúwa? Ní ìwọ ó máa bínú títí láé? Yóò ti pẹ́ tó ti owú rẹ yóò ha jò bí iná? 6Tú ìbínú rẹ jáde sí orílẹ̀-èdè tí kò ní ìmọ̀ rẹ, lórí àwọn ìjọba tí kò pe orúkọ rẹ; 7nítorí wọ́n ti run Jakọbu wọ́n sì sọ ibùgbé rẹ di ahoro. 8Má ṣe ka ẹ̀ṣẹ̀ àwọn baba wa sí wa lọ́rùn jẹ́ kí àánú rẹ wá kánkán láti bá wa, nítorí tí a rẹ̀ wá sílẹ̀ gidigidi. 9Ràn wá lọ́wọ́, Ọlọ́run Olùgbàlà wa, fún ògo orúkọ rẹ; gbà wá kí o sì dárí ẹ̀ṣẹ̀ wa jì nítorí orúkọ rẹ.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.