Saamu 78:15
Psalms 78:15 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Ó sán àpáta ní aginjù ó sì fún wọn ní omi mímu lọ́pọ̀lọ́pọ̀ bí ẹni pé láti inú ibú wá.
Psalms 78:15 in English
Psalms 78:15 · Berean Standard Bible
He split the rocks in the wilderness and gave them drink as abundant as the seas.
Context
13Ó pín òkun ní yà, ó sì mú wọn kọjá
Ó mù kí omi náà dúró bi odi gíga. 14Ní ọ̀sán, ó fi ìkùùkuu àwọsánmọ̀ ṣe amọ̀nà wọn
àti ní gbogbo òru pẹ̀lú ìmọ́lẹ̀ iná. 15Ó sán àpáta ní aginjù
ó sì fún wọn ní omi mímu lọ́pọ̀lọ́pọ̀
bí ẹni pé láti inú ibú wá. 16Ó mú ìṣàn omi jáde láti inú àpáta
omi ṣíṣàn sílẹ̀ gẹ́gẹ́ bí odò. 17Wọ́n sì tún tẹ̀síwájú láti dẹ́ṣẹ̀ sí i
ní ìṣọ̀tẹ̀ sí Ọ̀gá-ògo ní aginjù.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.