Saamu 65:12
Psalms 65:12 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Pápá tútù ní aginjù ń kan àwọn òkè kéékèèké fi ayọ̀ di ara wọn ní àmùrè.
Psalms 65:12 in English
Psalms 65:12 · Berean Standard Bible
The pastures of the wilderness overflow; the hills are robed with joy.
Context
10Ìwọ fi bomirin sí aporo rẹ̀
ìwọ tẹ́ ògúlùtu rẹ̀;
ìwọ fi òjò mú ilẹ̀ rẹ̀ rọ̀,
o sì bùkún ọ̀gbìn rẹ̀. 11Ìwọ fi oore rẹ dé ọdún ní adé,
ọ̀rá ń kán ní ipa ọ̀nà rẹ. 12Pápá tútù ní aginjù ń kan
àwọn òkè kéékèèké fi ayọ̀ di ara wọn ní àmùrè. 13Agbo ẹran ni a fi wọ pápá tútù náà ní aṣọ;
àfonífojì ni a fi ọkà bò mọ́lẹ̀,
wọ́n hó fún ayọ̀, wọ́n ń kọrin pẹ̀lú.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.