Saamu 64:9
Psalms 64:9 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Gbogbo ènìyàn yóò máa bẹ̀rù wọn ó kéde iṣẹ́ Ọlọ́run wọn ó dúró lé ohun tí ó ṣe.
Psalms 64:9 in English
Psalms 64:9 · Berean Standard Bible
Then all mankind will fear and proclaim the work of God; so they will ponder what He has done.
Context
7Ṣùgbọ́n Ọlọ́run yóò ta wọ́n ní ọfà;
wọn ó sì gbọgbẹ́ lójijì. 8Ahọ́n wọn yóò sì dojú ìjà kọ wọ́n, yóò sì run wọ́n,
gbogbo ẹni tí ó bá rí wọn yóò sì mi orí fún wọn. 9Gbogbo ènìyàn yóò máa bẹ̀rù
wọn ó kéde iṣẹ́ Ọlọ́run
wọn ó dúró lé ohun tí ó ṣe. 10Jẹ́ kí olódodo kí ó yọ̀ nínú Olúwa
yóò sì rí ààbò nínú rẹ̀.
Gbogbo ẹni ìdúró ṣinṣin ní ọkàn yóò máa yìn ín.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.