Native Bible

Psalms 63:10 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Wọn ó ti ọwọ́ idà ṣubú wọn ó sì di jíjẹ fún kọ̀lọ̀kọ̀lọ̀.

Psalms 63:10 in English

Psalms 63:10 · Berean Standard Bible

They will fall to the power of the sword; they will become a portion for foxes.

Context

8Ọkàn mí fà sí ọ: ọwọ́ ọ̀tún rẹ gbé mi ró. 9Àwọn tí ó ń wá ọkàn mí ni a ó parun; wọn ó sọ̀kalẹ̀ lọ sí ìsàlẹ̀ ilẹ̀ ayé. 10Wọn ó ti ọwọ́ idà ṣubú wọn ó sì di jíjẹ fún kọ̀lọ̀kọ̀lọ̀. 11Ṣùgbọ́n ọba yóò yọ̀ nínú Ọlọ́run ẹni tí ó fi orúkọ Ọlọ́run búra yóò ṣògo ṣùgbọ́n ẹnu àwọn òpùrọ́ la ó pamọ́.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.