Saamu 55:3
Psalms 55:3 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Sí ohùn àwọn ọ̀tá ni, nítorí igbe àwọn ènìyàn búburú; nítorí wọ́n mú ìjìyà wá sórí mi, wọ́n sì kẹ́gàn mi nínú ìbínú wọn.
Psalms 55:3 in English
Psalms 55:3 · Berean Standard Bible
at the voice of the enemy, at the pressure of the wicked. For they release disaster upon me and revile me in their anger.
Context
1Fi etí sí àdúrà mi, Ọlọ́run,
má ṣe fi ojú pa ẹ̀bẹ̀ mi rẹ́: 2gbọ́ mi kí o sì dá mi lóhùn.
Èrò mi ń dà mí láàmú, èmi sì ń pariwo. 3Sí ohùn àwọn ọ̀tá ni,
nítorí igbe àwọn ènìyàn búburú;
nítorí wọ́n mú ìjìyà wá sórí mi,
wọ́n sì kẹ́gàn mi nínú ìbínú wọn. 4Ọkàn mi wà nínú ìrora pẹ̀lú;
ẹ̀rù ikú kọjú ìjà sí mi. 5Ìbẹ̀rù àti ìwárìrì wa sí ara mi;
ìbẹ̀rù ti bò mí mọ́lẹ̀.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.