Saamu 52:1
Psalms 52:1 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Èéṣe tí ìwọ fi ń ṣe féfé nínú ìwà ìkà, ìwọ alágbára ọkùnrin? Èéṣe tí ìwọ fi ń gbéraga nígbà gbogbo, ìwọ ẹni ẹ̀gàn níwájú Ọlọ́run?
Psalms 52:1 in English
Psalms 52:1 · Berean Standard Bible
Why do you boast of evil, O mighty man? The loving devotion of God endures all day long.
Context
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.