Saamu 44:7
Psalms 44:7 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
ṣùgbọ́n ìwọ fún wa ní ìṣẹ́gun lórí àwọn ọ̀tá wa, ìwọ sì ti dójúti àwọn tí ó kórìíra wa.
Psalms 44:7 in English
Psalms 44:7 · Berean Standard Bible
For You save us from our enemies; You put those who hate us to shame.
Context
5Nípasẹ̀ rẹ ni àwa ó bi àwọn ọ̀tá wa ṣubú;
nípasẹ̀ orúkọ rẹ ni àwa ó tẹ àwọn ọ̀tá tí ó dìde sí wa mọ́lẹ̀, 6èmi kì yóò gbẹ́kẹ̀lé ọrun mi,
idà mi kì yóò mú ìṣẹ́gun lórí àwọn ọ̀tá wá, 7ṣùgbọ́n ìwọ fún wa ní ìṣẹ́gun lórí àwọn ọ̀tá wa,
ìwọ sì ti dójúti àwọn tí ó kórìíra wa. 8Nínú Ọlọ́run àwa ń ṣògo ní gbogbo ọjọ́,
àwa ó sì yin orúkọ rẹ títí láé. Sela. 9Ṣùgbọ́n nísinsin yìí, ìwọ ti kọ̀ wá, ìwọ sì ti dójútì wá,
Ìwọ kò sì bá àwọn ọmọ-ogun wa jáde mọ́.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.