Native Bible

Psalms 41:12 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Bí ó ṣe tèmi ni ìwọ dì mímú nínú ìwà òtítọ́ mi ìwọ sì gbé mi kalẹ̀ níwájú rẹ títí láé.

Psalms 41:12 in English

Psalms 41:12 · Berean Standard Bible

In my integrity You uphold me and set me in Your presence forever.

Context

10Ṣùgbọ́n ìwọ Olúwa, ṣàánú fún mi; gbé mi sókè, kí ń ba lè san fún wọn. 11Èmi mọ̀ pé inú rẹ̀ dùn sí mi, nítorí ọ̀tá mi kò borí mi. 12Bí ó ṣe tèmi ni ìwọ dì mímú nínú ìwà òtítọ́ mi ìwọ sì gbé mi kalẹ̀ níwájú rẹ títí láé. 13Olùbùkún ni Olúwa, Ọlọ́run Israẹli, láé àti láéláé. Àmín àti Àmín.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.