Saamu 149:7
Psalms 149:7 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Láti gba ẹ̀san lára àwọn orílẹ̀-èdè, àti ìjìyà lára àwọn ènìyàn,
Psalms 149:7 in English
Psalms 149:7 · Berean Standard Bible
to inflict vengeance on the nations and punishment on the peoples,
Context
5Jẹ́ kí àwọn ènìyàn mímọ́ kí ó yọ̀ nínú ọlá rẹ̀
kí wọn kí ó máa kọrin fún ayọ̀ ní orí ibùsùn wọn. 6Kí ìyìn Ọlọ́run kí ó wà ní ẹnu wọn
àti idà olójú méjì ní ọwọ́ wọn. 7Láti gba ẹ̀san lára àwọn orílẹ̀-èdè,
àti ìjìyà lára àwọn ènìyàn, 8láti fi ẹ̀wọ̀n de àwọn ọba wọn
àti láti fi ṣẹ́kẹ́ṣẹkẹ̀
irin de àwọn ọlọ́lá wọn. 9Láti ṣe ìdájọ́ tí àkọsílẹ̀ rẹ̀ sí wọn
èyí ni ògo àwọn ènìyàn mímọ́ rẹ̀.
Ẹ fi ìyìn fún Olúwa.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.