Saamu 142:6
Psalms 142:6 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Fi etí sí igbe mi, nítorí tí èmi wà nínú àìnírètí gbà mí lọ́wọ́ àwọn tí ń lépa mi, nítorí wọ́n lágbára jù mí lọ.
Psalms 142:6 in English
Psalms 142:6 · Berean Standard Bible
Listen to my cry, for I am brought quite low. Rescue me from my pursuers, for they are too strong for me.
Context
4Wo ọwọ́ ọ̀tún mi kí ó sì rì i
kò sí ẹni tí ó ṣe àníyàn mi
èmi kò ní ààbò;
kò sí ẹni tí ó náání ọkàn mi. 5Èmi kígbe sí ọ, Olúwa:
èmi wí pé, “Ìwọ ni ààbò mi,
ìpín mi ní ilẹ̀ alààyè.” 6Fi etí sí igbe mi,
nítorí tí èmi wà nínú àìnírètí
gbà mí lọ́wọ́ àwọn tí ń lépa mi,
nítorí wọ́n lágbára jù mí lọ. 7Mú ọkàn mi jáde kúrò nínú túbú,
kí èmi lè máa yin orúkọ rẹ.
Nígbà náà ni àwọn olódodo yóò yí mi káàkiri
nítorí ìwọ yóò fi ọ̀pọ̀lọpọ̀ wọn ba mi ṣe.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.