Native Bible

Psalms 137:4 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Àwa ó ti ṣe kọ orin Olúwa ní ilẹ̀ àjèjì

Psalms 137:4 in English

Psalms 137:4 · Berean Standard Bible

How can we sing a song of the LORD in a foreign land?

Context

2Àwa fi dùùrù wa kọ́ sí orí igi wílò, tí ó wà láàrín rẹ̀. 3Nítorí pé níbẹ̀ ni àwọn tí ó kó wa ní ìgbèkùn béèrè orin lọ́wọ́ wa, àti àwọn tí ó ni wá lára béèrè ìdárayá; wọn wí pé, “Ẹ kọ orin Sioni kan fún wa!” 4Àwa ó ti ṣe kọ orin Olúwa ní ilẹ̀ àjèjì 5Jerusalẹmu, bí èmi bá gbàgbé rẹ jẹ́ kí ọwọ́ ọ̀tún mi kí ó gbàgbé ìlò rẹ̀. 6Bí èmi kò bá rántí rẹ, jẹ́ kí ahọ́n mi kí ó lẹ̀ mọ́ èrìgì mi; bí èmi kò bá fi Jerusalẹmu ṣáájú olórí ayọ̀ mi gbogbo.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.