Native Bible

Psalms 13:6 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Èmi ó máa kọrin sí Olúwa, nítorí ó dára sí mi.

Psalms 13:6 in English

Psalms 13:6 · Berean Standard Bible

I will sing to the LORD, for He has been good to me.

Context

4Ọ̀tá mi wí pé, “Èmi ti ṣẹ́gun rẹ̀,” àwọn ọ̀tá mi yóò yọ̀ tí mo bá ṣubú. 5Ṣùgbọ́n mo gbẹ́kẹ̀lé ìfẹ́ rẹ tí kì í kùnà; ọkàn mi ń yọ̀ nínú ìgbàlà rẹ. 6Èmi ó máa kọrin sí Olúwa, nítorí ó dára sí mi.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.