Saamu 127:5
Psalms 127:5 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Ìbùkún ni fún ọkùnrin náà tí apó rẹ̀ kún fún wọn; ojú kì yóò tì wọ́n, ṣùgbọ́n wọn yóò ṣẹ́gun àwọn ọ̀tá ní ẹnu-ọ̀nà.
Psalms 127:5 in English
Psalms 127:5 · Berean Standard Bible
Blessed is the man whose quiver is full of them. He will not be put to shame when he confronts the enemies at the gate.
Context
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.