Saamu 119:84
Psalms 119:84 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Báwo ni ìránṣẹ́ rẹ̀ yóò ṣe dúró pẹ́ tó? Nígbà wo ni ìwọ yóò bá àwọn tí ń ṣe inúnibíni sí mi wí?
Psalms 119:84 in English
Psalms 119:84 · Berean Standard Bible
How many days must Your servant wait?* When will You execute judgment on my persecutors?
Context
82Ojú mi kùnà, pẹ̀lú wíwo ìpinnu rẹ;
èmi wí pé, “Nígbà wo ni ìwọ yóò tù mí nínú?” 83Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé èmi dàbí awọ-wáìnì lójú èéfín,
èmi kò gbàgbé ìlànà rẹ. 84Báwo ni ìránṣẹ́ rẹ̀ yóò ṣe dúró pẹ́ tó?
Nígbà wo ni ìwọ yóò bá àwọn
tí ń ṣe inúnibíni sí mi wí? 85Àwọn agbéraga wa ihò ìṣubú fún mi,
tí ó lòdì sí òfin rẹ. 86Gbogbo àṣẹ rẹ yẹ ní ìgbẹ́kẹ̀lé;
ràn mí lọ́wọ́, nítorí ènìyàn ń ṣe inúnibíni sí mi láìnídìí.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.