Saamu 119:8
Psalms 119:8 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Èmi yóò gbọ́rọ̀ sí àṣẹ rẹ̀, má ṣe kọ̀ mí sílẹ̀ pátápátá.
Psalms 119:8 in English
Psalms 119:8 · Berean Standard Bible
I will keep Your statutes; do not utterly forsake me.
Context
6Nígbà náà, ojú kò ní tì mí
nígbà tí mo bá ń kíyèsi àṣẹ rẹ̀ gbogbo. 7Èmi yóò yìn ọ́ pẹ̀lú ọkàn ìdúró ṣinṣin
bí èmi bá ti kọ́ òfin òdodo rẹ̀. 8Èmi yóò gbọ́rọ̀ sí àṣẹ rẹ̀,
má ṣe kọ̀ mí sílẹ̀ pátápátá. 9Báwo ni àwọn ọ̀dọ́ yóò ti ṣe pa ọ̀nà rẹ̀ mọ́?
Láti máa gbé ní ìbámu sí ọ̀rọ̀ rẹ. 10Èmi wá ọ pẹ̀lú gbogbo ọkàn mi
má ṣe jẹ́ kí èmi yapa kúrò nínú àṣẹ rẹ.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.