Saamu 119:24
Psalms 119:24 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Òfin rẹ ni dídùn inú mi; àwọn ní olùbádámọ̀ràn mi.
Psalms 119:24 in English
Psalms 119:24 · Berean Standard Bible
Your testimonies are indeed my delight; they are my counselors.
Context
22Mú ẹ̀gàn àti àbùkù kúrò lára mi,
nítorí èmi pa òfin rẹ mọ́. 23Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé àwọn alákòóso kójọpọ̀,
wọ́n ń sọ̀rọ̀ ìbàjẹ́ sí mi,
ṣùgbọ́n ìránṣẹ́ rẹ ń ṣe àṣàrò nínú àṣẹ rẹ. 24Òfin rẹ ni dídùn inú mi;
àwọn ní olùbádámọ̀ràn mi. 25Ọkàn mí lẹ̀ mọ́ erùpẹ̀;
ìwọ sọ mí di ààyè gẹ́gẹ́ bí ọ̀rọ̀ rẹ. 26Èmi tún ọ̀nà mi ṣírò ìwọ sì dá mi lóhùn;
kọ́ mi ní àṣẹ rẹ.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.