Saamu 119:102
Psalms 119:102 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Èmi kò yà kúrò nínú òfin rẹ, nítorí ìwọ fúnra rẹ̀ ni ó kọ́ mi.
Psalms 119:102 in English
Psalms 119:102 · Berean Standard Bible
I have not departed from Your ordinances, for You Yourself have taught me.
Context
100Èmi ni òye ju àwọn àgbà lọ,
nítorí mo gba ẹ̀kọ́ rẹ. 101Èmi ti pa ẹsẹ̀ mi mọ́ nínú gbogbo ọ̀nà ibi
nítorí kí èmi lè gba ọ̀rọ̀ rẹ. 102Èmi kò yà kúrò nínú òfin rẹ,
nítorí ìwọ fúnra rẹ̀ ni ó kọ́ mi. 103Báwo ni ọ̀rọ̀ rẹ̀ ṣe dùn mọ́ mi lẹ́nu tó,
ó dùn ju oyin lọ ní ẹnu mi! 104Èmi rí òye gbà nínú ẹ̀kọ́ rẹ;
nítorí náà èmi kórìíra gbogbo ọ̀nà tí kò tọ́.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.