Native Bible

Psalms 113:2 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Fi ìbùkún fún orúkọ Olúwa láti ìsinsin yìí lọ àti títí láéláé.

Psalms 113:2 in English

Psalms 113:2 · Berean Standard Bible

Blessed be the name of the LORD both now and forevermore.

Context

1Ẹ máa yin Olúwa. Yìn ín ẹ̀yin ìránṣẹ́ Olúwa, ẹ yin orúkọ Olúwa. 2Fi ìbùkún fún orúkọ Olúwa láti ìsinsin yìí lọ àti títí láéláé. 3Láti ìlà-oòrùn títí dé ìwọ̀ rẹ̀ orúkọ Olúwa ni kí a máa yìn. 4Olúwa ga lórí gbogbo orílẹ̀-èdè, àti ògo rẹ̀ lórí àwọn ọ̀run.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.