Native Bible

Psalms 109:2 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

nítorí àwọn ènìyàn búburú àti ẹlẹ́tàn ti ya ẹnu wọn sí mi wọ́n ti fi ahọ́n èké sọ̀rọ̀ sí mi.

Psalms 109:2 in English

Psalms 109:2 · Berean Standard Bible

For wicked and deceitful mouths open against me; they speak against me with lying tongues.

Context

1Ọlọ́run, ti èmi ń fi ìyìn fún, má ṣe dákẹ́, 2nítorí àwọn ènìyàn búburú àti ẹlẹ́tàn ti ya ẹnu wọn sí mi wọ́n ti fi ahọ́n èké sọ̀rọ̀ sí mi. 3Wọ́n fi ọ̀rọ̀ ìríra yí mi káàkiri; wọ́n bá mi jà láìnídìí 4Nípò ìfẹ́ mi, wọn ń ṣe ọ̀tá mi, ṣùgbọ́n èmi ń gba àdúrà.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.