Òwe 8:25
Proverbs 8:25 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
kí a tó fi àwọn òkè sí ipò wọn, ṣáájú àwọn òkè ni a ti bí mi,
Proverbs 8:25 in English
Proverbs 8:25 · Berean Standard Bible
Before the mountains were settled, before the hills, I was brought forth,
Context
23a ti yàn mí láti ayérayé,
láti ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀, kí ayé tó bẹ̀rẹ̀. 24Nígbà tí kò tí ì sí Òkun, ni a ti bí mi,
nígbà tí kò tí ì sí ìsun tí ó ní omi nínú; 25kí a tó fi àwọn òkè sí ipò wọn,
ṣáájú àwọn òkè ni a ti bí mi, 26kí ó tó dá ilẹ̀ ayé tàbí àwọn oko rẹ̀
tàbí èyíkéyìí nínú eruku ayé. 27Mo wà níbẹ̀ nígbà tí ó fi àwọn ọ̀run sí ipò wọn,
nígbà tí ó fi òsùwọ̀n àyíká sórí ibú omi,
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.