Òwe 24:19
Proverbs 24:19 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Má ṣe fòyà nítorí àwọn ènìyàn ibi tàbí jowú àwọn ènìyàn búburú,
Proverbs 24:19 in English
Proverbs 24:19 · Berean Standard Bible
Do not fret over evildoers, and do not be envious of the wicked.
Context
17Má ṣe yọ̀ nígbà tí ọ̀tá rẹ bá ṣubú;
nígbà tí ó bá kọsẹ̀, má ṣe jẹ́ kí ọkàn rẹ kí ó yọ̀. 18Àìṣe bẹ́ẹ̀ Olúwa yóò rí i yóò sì bínú
yóò sì yí ìbínú rẹ̀ padà kúrò lọ́dọ̀ rẹ̀. 19Má ṣe fòyà nítorí àwọn ènìyàn ibi
tàbí jowú àwọn ènìyàn búburú, 20nítorí ẹni ibi kò ní ìrètí ọjọ́ iwájú
a ó sì pa fìtílà àwọn ènìyàn búburú kú. 21Bẹ̀rù Olúwa àti ọba, ọmọ mi,
má sì ṣe darapọ̀ pẹ̀lú àwọn olórí kunkun.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.