Òwe 20:26
Proverbs 20:26 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Ọlọ́gbọ́n ọba tú ènìyàn búburú ká; Ó sì fi òòlọ ìpakà lọ̀ wọ́n.
Proverbs 20:26 in English
Proverbs 20:26 · Berean Standard Bible
A wise king separates out the wicked and drives the threshing wheel over them.
Context
24Olúwa ni ó ń ṣe olùdarí ìgbésẹ̀ ènìyàn.
Báwo wá ni òye gbogbo ọ̀nà ènìyàn ṣe le yé ni? 25Ìdẹ̀kùn ni fún ènìyàn láti ṣe ìlérí kíákíá
nígbà tí ó bá sì yá kí ó máa ro ẹ̀jẹ̀ rẹ̀ wò. 26Ọlọ́gbọ́n ọba tú ènìyàn búburú ká;
Ó sì fi òòlọ ìpakà lọ̀ wọ́n. 27Àtùpà Olúwa ń ṣe àwárí ẹ̀mí ènìyàn
a máa ṣàwárí ibi ìkọ̀kọ̀ inú. 28Ìfẹ́ àti òdodo pa ọba mọ́,
nípa ìfẹ́, ìtẹ́ rẹ̀ wà láìléwu.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.