Òwe 16:33
Proverbs 16:33 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
A ṣẹ́ kèké si ìṣẹ́po aṣọ, ṣùgbọ́n gbogbo ìdájọ́ rẹ̀ wá láti ọ̀dọ̀ Olúwa.
Proverbs 16:33 in English
Proverbs 16:33 · Berean Standard Bible
The lot is cast into the lap, but its every decision is from the LORD.
Context
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.