Òwe 14:6
Proverbs 14:6 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Ẹlẹ́gàn ń wá ọgbọ́n kò sì rí rárá, ṣùgbọ́n ìmọ̀ máa ń wà fún olóye.
Proverbs 14:6 in English
Proverbs 14:6 · Berean Standard Bible
A mocker seeks wisdom and finds none, but knowledge comes easily to the discerning.
Context
4Níbi tí kò sí ẹran, ibùjẹ ẹran a máa mọ́ tónítóní,
ṣùgbọ́n, nípa agbára akọ màlúù ni ọ̀pọ̀ ìkórè ti ń wá. 5Ẹlẹ́rìí tí ń ṣọ òtítọ́ kì í tan ni
ṣùgbọ́n ẹlẹ́rìí èké a máa tú irọ́ jáde. 6Ẹlẹ́gàn ń wá ọgbọ́n kò sì rí rárá,
ṣùgbọ́n ìmọ̀ máa ń wà fún olóye. 7Má ṣe súnmọ́ aláìgbọ́n ènìyàn,
nítorí ìwọ kì yóò rí ìmọ̀ ní ètè rẹ̀. 8Ọgbọ́n olóye ni láti ronú jinlẹ̀ nípa ọ̀nà wọn
ṣùgbọ́n ìwà òmùgọ̀ aṣiwèrè ni ìtànjẹ.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.