Òwe 14:33
Proverbs 14:33 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Ọgbọ́n wà nínú ọkàn olóye kódà láàrín àwọn aláìlóye, ó jẹ́ kí wọn mọ òun.
Proverbs 14:33 in English
Proverbs 14:33 · Berean Standard Bible
Wisdom rests in the heart of the discerning; even among fools she is known.*
Context
31Ẹni tí ó fi ìyà jẹ aláìní ń fi ìkórìíra hàn
ṣùgbọ́n ẹnikẹ́ni tí ó ṣoore fún aláìní bu ọlá fún Ọlọ́run. 32Nígbà tí ìyọnu bá dé, a fa àwọn búburú lulẹ̀,
kódà nínú ikú àwọn olódodo ni ààbò. 33Ọgbọ́n wà nínú ọkàn olóye
kódà láàrín àwọn aláìlóye, ó jẹ́ kí wọn mọ òun. 34Òdodo a máa gbé orílẹ̀-èdè lékè,
ṣùgbọ́n ìtìjú ni ẹ̀ṣẹ̀ jẹ́ fún àwùjọ káwùjọ. 35Ọba a máa ní inú dídùn sí ìránṣẹ́ tí ó gbọ́n
ṣùgbọ́n ìbínú rẹ̀ wá sórí ìránṣẹ́ adójútini.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.