Òwe 14:19
Proverbs 14:19 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Ènìyàn ìkà yóò tẹríba níwájú àwọn ènìyàn rere àti ènìyàn búburú níbi ìlẹ̀kùn àwọn olódodo.
Proverbs 14:19 in English
Proverbs 14:19 · Berean Standard Bible
The evil bow before the good, and the wicked at the gates of the righteous.
Context
17Ẹni tí ó máa ń tètè bínú máa ń hùwà aṣiwèrè,
a sì kórìíra eléte ènìyàn. 18Òpè jogún ìwà òmùgọ̀
ṣùgbọ́n a dé ọlọ́gbọ́n ní adé ìmọ̀. 19Ènìyàn ìkà yóò tẹríba níwájú àwọn ènìyàn rere
àti ènìyàn búburú níbi ìlẹ̀kùn àwọn olódodo. 20Kódà àwọn aládùúgbò tálákà kò fẹ́ràn rẹ̀,
ṣùgbọ́n, ọlọ́rọ̀ ní ọ̀rẹ́ púpọ̀. 21Ẹni tí ó kẹ́gàn aládùúgbò o rẹ̀ ti dẹ́ṣẹ̀
ṣùgbọ́n ìbùkún ni fún ẹni tí ó ṣàánú àwọn aláìní.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.