Native Bible

Numbers 7:76 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

akọ ewúrẹ́ fún ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀;

Numbers 7:76 in English

Numbers 7:76 · Berean Standard Bible

one male goat for a sin offering;

Context

74àwo wúrà kan tí ìwọ̀n rẹ̀ jẹ́ ṣékélì mẹ́wàá tí ó kún fún tùràrí; 75akọ ọ̀dọ́ màlúù kan, àgbò kan àti akọ ọ̀dọ́-àgùntàn ọlọ́dún kan fún ẹbọ sísun; 76akọ ewúrẹ́ fún ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀; 77màlúù méjì, àgbò márùn-ún, akọ ewúrẹ́ márùn-ún àti akọ ọ̀dọ́-àgùntàn ọlọ́dún kan márùn-ún, tí wọn ó fi rú ẹbọ àlàáfíà. Èyí ni ọrẹ Pagieli ọmọ Okanri. 78Ahira ọmọ Enani, olórí àwọn Naftali ni ó mú ọrẹ rẹ̀ wá ní ọjọ́ kejìlá.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.