Numeri 7:64
Numbers 7:64 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
akọ ewúrẹ́ kan fún ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀;
Numbers 7:64 in English
Numbers 7:64 · Berean Standard Bible
one male goat for a sin offering;
Context
62àwo wúrà kan tí ìwọ̀n rẹ̀ jẹ́ ṣékélì mẹ́wàá tí ó kún fún tùràrí; 63akọ ọ̀dọ́ màlúù kan, àgbò kan àti akọ ọ̀dọ́-àgùntàn ọlọ́dún kan fún ẹbọ sísun; 64akọ ewúrẹ́ kan fún ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀; 65màlúù méjì, àgbò márùn-ún, akọ ewúrẹ́ márùn-ún àti akọ ọ̀dọ́-àgùntàn ọlọ́dún kan márùn-ún tí wọn ó fi rú ẹbọ àlàáfíà.
Èyí ni ọrẹ Abidani ọmọ Gideoni. 66Ahieseri ọmọ Ammiṣaddai, olórí àwọn ọmọ Dani ni ó mú ọrẹ tirẹ̀ wá ní ọjọ́ kẹwàá.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.