Numeri 7:28
Numbers 7:28 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
akọ ewúrẹ́ kan fún ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀;
Numbers 7:28 in English
Numbers 7:28 · Berean Standard Bible
one male goat for a sin offering;
Context
26àwo wúrà kan tí ìwọ̀n rẹ̀ jẹ́ ṣékélì mẹ́wàá tí ó kún fún tùràrí; 27akọ ọ̀dọ́ màlúù kan, àgbò kan àti akọ ọ̀dọ́-àgùntàn ọlọ́dún kan fún ẹbọ sísun; 28akọ ewúrẹ́ kan fún ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀; 29Màlúù méjì, àgbò márùn-ún, òbúkọ márùn-ún akọ ọ̀dọ́-àgùntàn ọlọ́dún kan márùn-ún tí wọn o fi rú ẹbọ àlàáfíà.
Èyí ni ọrẹ Eliabu ọmọ Heloni. 30Elisuri ọmọ Ṣedeuri olórí àwọn ọmọ Reubeni ni ó mú ọrẹ wá ní ọjọ́ kẹrin.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.