Numeri 2:1
Numbers 2:1 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Olúwa sọ fún Mose àti Aaroni pé,
Numbers 2:1 in English
Numbers 2:1 · Berean Standard Bible
Then the LORD said to Moses and Aaron:
Context
1Olúwa sọ fún Mose àti Aaroni pé, 2“Kí àwọn ọmọ Israẹli pa àgọ́ wọn yí àgọ́ ìpàdé ká, kí wọ́n jẹ́ kí àgọ́ wọn jìnnà sí i díẹ̀, oníkálùkù lábẹ́ ọ̀págun pẹ̀lú àsíá ìdílé wọn.” 3Ní ìlà-oòrùn, ní ìdojúkọ àtiyọ oòrùn:
ni kí ìpín ti Juda pa ibùdó wọn sí lábẹ́ ọ̀págun wọn. Olórí Juda ni Nahiṣoni ọmọ Amminadabu.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.